Liberia
(Àtúnjúwe láti Làìbéríà)
Làìbéríà tabi Orile-ede Olominira ile Làìbéríà je orile-ede ni Iwoorun Afrika. O fi ègbé kan Ilè Sàró tí a mò si Sierra Leone ní ìwǫ oòrùn, orílę èdè Guinea ni gúúsù ati orílę èdè Côte d'Ivoire ní ìlà oòrùn. Etí Òkun Làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ìtélè ewéko gbígbe. Ilu naa ni o ni 40% ninu eyi ti o seku ni igi Iju Guinea ti Apa Guusu. Afefe ilu Làìbéríà je ti gbigbona ila idameji aye, pelu òjo pupo ni osu May titi di osu October ni asiko òjò ati afefe oye lile fun iyoku odun.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Làìbéríà Republic of Liberia | |
---|---|
Motto: "The love of liberty brought us here" | |
Orin ìyìn: All Hail, Liberia, Hail! | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Monrovia |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English |
Orúkọ aráàlú | Liberian |
Ìjọba | Presidential republic |
• Aare | Joseph Boakai |
Jeremiah Koung | |
Sie-A-Nyene Yuoh | |
Formation| Idasile ile Làìbéríà | |
• ACS colonies consolidation | 1821-1842 |
• Ilominira (latowo Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà) | 26 July 1847 |
Ìtóbi | |
• Total | 111,369 km2 (43,000 sq mi) (103rd) |
• Omi (%) | 13.514 |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 3,955,000[1] |
• 2008 census | 3,476,608 (130th) |
• Ìdìmọ́ra | 35.5/km2 (91.9/sq mi) (180th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $1.556 billion[2] |
• Per capita | $424[2] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $876 million[2] |
• Per capita | $239[2] |
HDI (2007) | ▲ 0.442 Error: Invalid HDI value · 169th |
Owóníná | Liberian dollar1 (LRD) |
Ibi àkókò | GMT |
• Ìgbà oru (DST) | not observed |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | 231 |
Internet TLD | .lr |
1 United States dollar also in common usage. |
Àwọn Ìtọ́ka sí àtúnṣe
- ↑ Department of Economic and Social AffairsPopulation Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "Liberia". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́GoogleOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìaue27qi31gzr5oozoe29Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)OmiPàtàkì:SearchPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÀrokòÈdè YorùbáFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgEre idarayaÀṣà YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáMọ́skòBD MimọWikipedia:Èbúté ÀwùjọLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Wikipedia:Abẹ́ igiÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáAkanlo-edeWikipedia:Nípa Wiki HowWikipedia:Contact usÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOwe YorubaÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíWiki HowIndonésíàÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáC++PornhubWikiISBNWikipedia:NípaEzra OlubiLinda Ikeji