Figueira Cid
Figueira Cid (tí wọ́n bí ní 18 Oṣù Kínní, Ọdún 1957), jẹ́ òṣèrékùnrin, olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Pọ́rtúgàl.[1][2]Ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ilẹ̀ Yúróòpù àti ilẹ̀ Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu àwọn fíìmù bíi Ministério do Tempo, Até Amanhã, Camaradas àti The masked avenger: Lagardère.[3]
Figueira Cid | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Figueira Cid 18 Oṣù Kínní 1957 Lisbon, Portugal |
Orílẹ̀-èdè | Portuguese |
Iṣẹ́ | Actor, director, writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1983–present |
Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe
Àwọn ìtakùn Ìjásóde àtúnṣe
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÒgún LákáayéPàtàkì:SearchWikipedia:Nípa Wiki HowWiki HowWikipedia:Èbúté ÀwùjọFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)67085 OppenheimerEre idarayaErin-Ijesha WaterfallsÀṣà YorùbáÀrokòÈdè YorùbáIṣẹ́ẹ̀rọ onítannáFiennaOmiFáìlì:Gesupietrochiave.jpgWikipedia:Abẹ́ igiFáìlì:HDFRE V4 D477 Restoration of the Byzantine citadelle of Haidra Tunisia, after Saladin.pngÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀17 SeptemberItan Ijapa ati AjaWikiWikipedia:Àyọkà pàtàkìÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáUttarakhandÀwọn Kààdì ÌsanwóOṣù Kínní 13IndonésíàPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáWikimediaWikipedia:Ìmúdára àyọkàÒrìṣà EgúngúnSikiru Ayinde Barrister