Marseille
- Marseille wa ni ipoidojuko 43°17′47″N 5°22′12″E / 43.296346°N 5.369889°ECoordinates: 43°17′47″N 5°22′12″E / 43.296346°N 5.369889°E
Marseille (ìpè Faransé: [maʁ.ˈsεj]) jẹ́ ìlú èbúté ìgbàanì, èyí tá a dá nǹkan bíi 600 ṣááju Sànmánì Tiwa, ní apá gúúsù-ìlàoòrùn Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 240.62 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 858,120 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe
- Ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù (Faransé) (Gẹ̀ẹ́sì) (Híspánì)
- Ìrìn-àjò Afẹ́ (Faransé) (Gẹ̀ẹ́sì) (Jẹ́mánì) (Híspánì) (Chinese)
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)MontanaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunEre idarayaỌ̀sẹ̀Ògún LákáayéPàtàkì:SearchSimeon Adebo LibraryÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáMọ́remí ÁjàṣoroÈdè YorùbáÀrokòWiki HowWikipedia:Nípa Wiki HowWikipedia:Èbúté ÀwùjọGbólóhùn YorùbáOwe YorubaÀyèọmọìlúFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgISBNIṣẹ́ Àgbẹ̀Ayájọ́ ọjọ́ òṣìṣẹ́ lágbàáyéÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Wikipedia:Abẹ́ igiFáwẹ̀lì YorùbáÌrànwọ́:Àwọn àtúnṣe tuntunPornhubOmiAkanlo-edeHermann HesseOrúkọ YorùbáNgozi EzeonuṢàngó