Aṣọ
Aṣọ jé ohun tí ènìyàń ń wọ̀ láti bo ìhòhò. Oríṣi ohun èlò ni a fi ń hun aṣọ, àwọn ohun èlò bíi òwú, ọ̀rá, awọ sílìkì[1] àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, lẹ́yìn híhun aṣọ, aṣọ tún nílò rírán kí ó tó le di wíwọ̀. Yàtò sí fún bíbo ìhòhò, aṣọ tún wà fún oge àti ìdánimọ. Àpẹẹrẹ oríṣi aṣọ ilé Yorùbá ni ìró àti bùbá, Agbádá, dànsíkí, búbù, kẹ̀mbẹ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. (ní òpòlopò ìgbà) olùwọ àwọn asọ wọ̀nyí ma ń jé ọmọ Yorùbá [2] [3].
Orisirisi aso ní ilè Yorùbá
àtúnṣe• Agbádá
• Ìpèlé
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ Objective, Common (2021-12-10). "What Are Our Clothes Made From?". Common Objective. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ Lawal, Babatunde (2013-10-04). "Agbada Clothing". LoveToKnow. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ BB, Miss (2015-08-14). "The evolution of Iro and Buba - BLACK AND BEAUTIFUL". BLACK AND BEAUTIFUL. Retrieved 2022-03-01.
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWiki HowWikipedia:Nípa Wiki HowFiennaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọÒgún LákáayéFinidi GeorgeWikimedia CommonsÀṣà YorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Fáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgỌdún IléyáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáÀsìá ilẹ̀ PakístànÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÈṣùÀrokòWikipedia:Abẹ́ igiWikipedia:Contact usPàtàkì:SearchMediaWikiOhun ìgboroNetwork Time ProtocolWikipedia:Ìkìlọ̀ gbogboTim Berners-LeeÈdè YorùbáẸ̀ka:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ISO 8601Àrún èrànkòrónà ọdún 2019ISBNGuglielmo MarconiWikipedia:Àyọkà pàtàkìOrílẹ̀ èdè AmericaÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáAyájọ́ ọjọ́ òṣìṣẹ́ lágbàáyéFáìlì:Watch Football Streams.png