Amóráìtì
''Amorite'' je Èdè Sẹ̀mítíìkì (Semitic) kan ni Amóráìtì (Amorite) tí wọ́n ń sọ ní agbègbè àríwá Síríà (Syria) òde òní ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì ọdún sí ẹgbẹ̀rún kan àbọ̀ ṣáájú ìbí Kírísítì. Díẹ̀ ni a mọ̀ nípa èdè yìí nítorí pé láti inú orúkọ ènìyàn àti àwọn àkọ́sílẹ̀ díẹ̀ tí a rí tí wọ́n opẹ́ sí ara òkúta nìkan ni a mọ̀ nípa èdè yìí
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Àsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìPàtàkì:SearchÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáEre idarayaÀṣà YorùbáÀrokòÈdè YorùbáẸ̀ka:Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1895Owe YorubaIṣẹ́ Àgbẹ̀Iṣẹ́ẹ̀rọ onítannáWikipedia:Nípa Wiki HowÒgún LákáayéFáwẹ̀lì YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọAkanlo-edeÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáFínlándìẸ̀ka:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́LátfíàWiki HowÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíGírámà YorùbáWikipedia:Abẹ́ igiṢàngóPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunTamil NaduMọ́remí ÁjàṣoroISBNÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáMediaWikiỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Ìbálòpọ̀OmiPuducherryMayotte