Marie Curie
Marie Salomea Skłodowska-Curie (7 November 1867 – 4 July 1934) je onimo fisiyiki ati onimo kemistri omo orile-ede Poland to di ara Fransi lojowaju. O je asiwaju ninu papa radiolilagbara ati eni akoko to gba Ebun Nobel meji[1] — ninu fisiyiki ati kemistri. Ohun na lo tun je obinrin akoko to je ojogbon ni Yunifasiti ilu Paris.
Marie Skłodowska–Curie | |
---|---|
Ìbí | Warsaw, Vistula Land, Russian Empire | 7 Oṣù Kọkànlá 1867
Aláìsí | 4 July 1934 Passy, France | (ọmọ ọdún 66)
Ará ìlẹ̀ | Rosia, niwaju Fransi |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Polandi |
Pápá | physics, chemistry |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Paris |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Paris ESPCI |
Doctoral advisor | Henri Becquerel |
Doctoral students | André-Louis Debierne Óscar Moreno Marguerite Catherine Perey |
Ó gbajúmọ̀ fún | radioactivity, polonium, radium |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1903) Davy Medal (1903) Matteucci Medal (1904) Nobel Prize in Chemistry (1911) |
Religious stance | Agnostic |
Notes She is the only person to win Nobel Prizes in two sciences. She was the wife of Pierre Curie, and the mother of Irene Joliot-Curie and Ève Curie. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi àtúnṣe
- ↑ "Nobel Laureate Facts". Retrieved 26 November 2008.
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Pàtàkì:SearchOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Abẹ́ igiÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Nípa Wiki HowWikiWiki HowÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáAustrálíàỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈdè YorùbáÌrànlọ́wọ́:Ẹ̀kaÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀrokòDiamond JacksonIṣẹ́ Àgbẹ̀Ìbálòpọ̀MediaWikiApple Inc.67085 OppenheimerInternetYemojaOperating SystemLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Isaiah WashingtonÀṣà YorùbáÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánWikipedia:Contact usC++File Transfer ProtocolHTMLOwe YorubaKetia MbeluLinda Ikeji