Ìtàn
Ìtàn ni ìgbékalẹ̀ tàbí sísọ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ohun tí ó ti kọjá. Yòóbá bọ̀, wọ́n ní "bọ́mọdé kò bá gbọ́tàn, a gbọ́ àrọ́bá...." Ìtàn lè wà ní àkọsílẹ̀ tàbí kí ó máà ní àkọsílẹ̀. Ìtàn máa ń jẹ́ kí a mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ méèlegbàgbé tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ènìyàn kò sí láyé tàbí wà níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà. [1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe
- ↑ Hirst, K. Kris (2009-05-19). "What Is History, Anyway? A Handful of Historians Explain". ThoughtCo. Retrieved 2020-01-06.
- ↑ "What is History & Why Study It?". siena.edu. 2014-02-01. Archived from the original on 2014-02-01. Retrieved 2020-01-06. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Pàtàkì:SearchOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Abẹ́ igiÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Nípa Wiki HowWikiWiki HowÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáAustrálíàỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈdè YorùbáÌrànlọ́wọ́:Ẹ̀kaÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀrokòDiamond JacksonIṣẹ́ Àgbẹ̀Ìbálòpọ̀MediaWikiApple Inc.67085 OppenheimerInternetYemojaOperating SystemLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Isaiah WashingtonÀṣà YorùbáÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánWikipedia:Contact usC++File Transfer ProtocolHTMLOwe YorubaKetia MbeluLinda Ikeji